BBC News Yoruba

@bbcnewsyoruba

Bó ṣe ń lọ l'ágbàáyé lórí ìkànsíraẹni Instagram BBC Yorùbá #bbcnewsyoruba #bbcyoruba
Posts
15.9k
Followers
382k
Following
56
Account Insight
Score
68.96%
Index
Health Rate
80%
Users Ratio
6814:1
Weeks posts
19.52
BBC News Yoruba fọ̀rọ̀ wá Oluwatosin Olaniyan, @olaniyan_tosin tí àwọn èèyàn tún ń pè ní ‘Ìdààmú Industry’ lẹ́nu wò, ó sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé rẹ̀, eré tíátà, ọ̀rọ̀ ìfẹ́ àtawọn ohun míràn, àbọ̀ rèé: /yoruba/articles/c5y77wy465po
22.0k 355
1 month ago
Mo 'liké' owó, Baba mi ni mo fẹran, orin kíkọ àti orin Kwam 1 dáa- Raheem Okoya ọmọ Sade Okoya sọrọ lori awọn nkan to fẹran lori BBC Yoruba ...
19.4k 686
2 months ago
Njẹ́ o ti darapọ̀ mọ́ ìkànnì BBC Yoruba Whatsapp Chaanl? Má jẹ̀ ẹ́ kí wọ́n gbé nnkan gbẹ̀yìn rẹ o! Darapọ̀ mọ́ BBC New Yoruba lórí Whatsapp lónìí. Ó rọrùn púpọ̀ láti ṣe. Ṣáà ti wo fídíò yìí láti mọ bí o ṣe le darapọ̀.
91 430
1 year ago
Ìyàwó gómìnà ìpínlẹ̀ Jigawa, Hajiya Amina Umar Namadi, ti ṣe ìgbéyàwó fún àwọn ọmọ aláìlóbìí 300 lẹ́ẹ̀kanṣoṣo. Níbi ìgbéyàwó náà ni wọ́n ti so obìnrin 150 àti ọkùnrin 150 pọ̀. Ìyàwó gómìnà ọ̀hún sọ pé ìgbéyàwó náà wáyé láti mú ìrẹ́pọ́ wà láàrín àwọn aráàlú 📷Hajiya Amina Umar Namadi, /yoruba
2 0
50 minutes ago
Ààrẹ Bola Tinubu ló kéde bẹ́ẹ̀ níbi ìpàdé Africa CEO Forum tó wáyé nílùú Kigali, ní Rwanda. Àmọ́ ṣá, ọmọ Randa tó bá fẹ́ l[po kọjá ọgbọ̀n ọjọ́ ní Naijiria yóò nílò físà /yoruba
3 0
1 hour ago
Ẹ̀yin ti Anakaye FC, ẹ jáde o
5 0
2 hours ago
Ojúmọ́ ire ló mọ́ wa lónìí, ẹ jẹ́ ká jọ parí òwe wa
10 5
9 hours ago
Ọmọdekunrin kan ree, ti iya rẹ ji gbe lọmọ ọdun mọkanla, alaye ree lori oun to sẹlẹ si.
17 0
19 hours ago
Ó tún yá o. Ọ̀dọ̀ ta lẹ̀ ń gbé fáàjì gbà lópin ọ̀sẹ̀ nínú àwọn eléré ńlá yìí?
9 0
20 hours ago
Lori eto Agbole Akọni BBC News Yoruba, idile Ogboriefon ni ilu Ibadan ni a balẹ si lati mọ nipa bi akọni yii ṣe lo igbesi aye rẹ nigba to wa laye. /yoruba/articles/cn9p51wer5yo
59 1
22 hours ago
Bi ogun Iran se n waye, ni iwa ole jia lori okun tun n gbinlẹ si. Ẹ wo awakọ oju omi kan to ko sọwọ awọn ole ori okun, ti wọn fẹ paa. Se ni ọkunrin naa kigbe pe " ma pa mi, Musulumi ni mi, se Musulumi ni ẹ? Ọkan lara awọn ole oju omi naa fesi pada pe Musulumi ni oun. Amọ dipo ko pa awakọ oju omi naa, se lo mu ni igbekun.
23 0
1 day ago
A kú òwúrọ̀, ojúmọ́ ire ló mọ́ wa. Òwe wa tòní rèé, ẹ jẹ́ ká jọ parí ẹ̀
14 2
1 day ago