Bi ogun Iran se n waye, ni iwa ole jia lori okun tun n gbinlẹ si.
Ẹ wo awakọ oju omi kan to ko sọwọ awọn ole ori okun, ti wọn fẹ paa.
Se ni ọkunrin naa kigbe pe " ma pa mi, Musulumi ni mi, se Musulumi ni ẹ?
Ọkan lara awọn ole oju omi naa fesi pada pe Musulumi ni oun.
Amọ dipo ko pa awakọ oju omi naa, se lo mu ni igbekun.